Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 29:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní, nítorí ìwé tí o fi orúkọ ara rẹ kọ sí gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà ní Jerusalẹmu, ati sí Sefanaya alufaa, ọmọ Maaseaya, ati sí gbogbo àwọn alufaa, pé:

Ka pipe ipin Jeremaya 29

Wo Jeremaya 29:25 ni o tọ