Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 28:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn wolii tí wọ́n ti wà ṣáájú èmi pẹlu rẹ ní ìgbà àtijọ́ sọ àsọtẹ́lẹ̀ ogun, ìyàn, ati àjàkálẹ̀ àrùn nípa ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè ati nípa àwọn ìjọba ńláńlá.

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:8 ni o tọ