Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 28:6 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní, “Amin, kí OLUWA ṣe bẹ́ẹ̀. Kí OLUWA mú àsọtẹ́lẹ̀ tí o sọ ṣẹ, kí ó kó àwọn ohun èlò ilé rẹ̀ ati gbogbo àwọn eniyan tí a kó lẹ́rú lọ sí Babiloni pada sí ibí yìí.

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:6 ni o tọ