Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 28:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun óo mú Jehoiakini ọba Juda, ọmọ Jehoiakimu, ati gbogbo àwọn tí a kó lẹ́rú láti Juda lọ sí Babiloni pada sí ibí yìí, nítorí òun óo ṣẹ́ àjàgà ọba Babiloni. Ó ní OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:4 ni o tọ