Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 28:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Nítorí náà, OLUWA ní: òun óo mú ọ kúrò lórí ilẹ̀ ayé. Ní ọdún yìí gan-an ni o óo sì kú, nítorí pé o ti sọ ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀ sí OLUWA.”

17. Ní ọdún náà gan-an ní oṣù keje, ni Hananaya wolii kú.

Ka pipe ipin Jeremaya 28