Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 28:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kan náà, ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Sedekaya, ọba Juda, ní oṣù karun-un ọdún kẹrin, Hananaya wolii ọmọ Aṣuri, tí ó wá láti Gibeoni bá mi sọ̀rọ̀ ní ilé OLUWA lójú àwọn alufaa ati gbogbo àwọn eniyan pé,

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:1 ni o tọ