Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 26:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ìgbà Hesekaya ọba Juda, Mika ará Moreṣeti sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún gbogbo àwọn ará Juda pé OLUWA àwọn ọmọ ogun ní,‘A óo kọ Sioni bí ilẹ̀ oko,Jerusalẹmu yóo di òkítì àlàpà;òkè ilé yìí yóo sì di igbó kìjikìji.’

Ka pipe ipin Jeremaya 26

Wo Jeremaya 26:18 ni o tọ