Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 26:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ẹ mọ̀ dájú pé bí ẹ bá pa mí, ẹ óo fa ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sórí ara yín, ati ìlú yìí ati àwọn ará ìlú yìí, nítorí pé nítòótọ́ ni OLUWA rán mi pé kí n sọ gbogbo ohun tí mo sọ kí ẹ gbọ́.”

Ka pipe ipin Jeremaya 26

Wo Jeremaya 26:15 ni o tọ