Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 26:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ tún ọ̀nà yín ṣe, ẹ pa ìṣe yín dà, kí ẹ sì gbọ́ràn sí OLUWA Ọlọrun yín lẹ́nu, yóo sì yí ọkàn rẹ̀ pada kúrò ninu ibi tí ó sọ pé òun yóo ṣe sí i yín.

Ka pipe ipin Jeremaya 26

Wo Jeremaya 26:13 ni o tọ