Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 26:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ìjòyè Juda gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n lọ sí ilé OLUWA láti ààfin ọba, wọ́n sì jókòó ní Ẹnu Ọ̀nà Titun tí ó wà ní ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Jeremaya 26

Wo Jeremaya 26:10 ni o tọ