Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 25:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin olùṣọ́-aguntan, ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, ẹ kígbe. Ẹ̀yin oluwa àwọn agbo ẹran, ẹ máa yíra mọ́lẹ̀ ninu eérú nítorí àkókò tí a óo pa yín, tí a óo sì tu yín ká ti tó, ẹ óo sì ṣubú lulẹ̀ bí ẹran àbọ́pa.

Ka pipe ipin Jeremaya 25

Wo Jeremaya 25:34 ni o tọ