Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 25:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Fún ọdún mẹtalelogun, láti ọdún kẹtala tí Josaya ọmọ Amoni ti jọba Juda, títí di ọjọ́ òní, ni OLUWA ti ń bá mi sọ̀rọ̀, tí mo sì ti ń sọ ọ́ fun yín lemọ́lemọ́, ṣugbọn tí ẹ kò sì gbọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 25

Wo Jeremaya 25:3 ni o tọ