Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 25:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí aadọrin ọdún bá pé, n óo jẹ ọba Babiloni ati orílẹ̀-èdè rẹ̀, ati ilẹ̀ àwọn ará Kalidea níyà, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. N óo sì sọ ibẹ̀ di àlàpà títí ayé.

Ka pipe ipin Jeremaya 25

Wo Jeremaya 25:12 ni o tọ