Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹrin tí Jehoiakimu, ọmọ Josaya jọba ní Juda, tí ó jẹ́ ọdún kinni tí Nebukadinesari jọba Babiloni, Jeremaya wolii gbọ́ ọ̀rọ̀ OLUWA nípa gbogbo àwọn ará Juda.

Ka pipe ipin Jeremaya 25

Wo Jeremaya 25:1 ni o tọ