Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará Juda,ẹ má sọkún nítorí ọba tí ó kú,ẹ má sì dárò rẹ̀.Ọba tí ń lọ sí ìgbèkùn ni kí ẹ sọkún fún,nítorí pé yóo lọ, kò sì ní pada wá mọ́láti fojú kan ilẹ̀ tí a bí i sí.

Ka pipe ipin Jeremaya 22

Wo Jeremaya 22:10 ni o tọ