Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ti ìwọ Paṣuri, ati gbogbo àwọn ará ilé rẹ, wọn óo ko yín ní ìgbèkùn lọ sí Babiloni. Ibẹ̀ ni ẹ óo kú sí, ibẹ̀ ni wọ́n óo sì sin yín sí; àtìwọ, ati gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ tí ò ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́ fún.’ ”

Ka pipe ipin Jeremaya 20

Wo Jeremaya 20:6 ni o tọ