Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, nígbà tí Paṣuri tú Jeremaya sílẹ̀ ninu ààbà, Jeremaya wí fún un pé, “Kì í ṣe Paṣuri ni OLUWA pe orúkọ rẹ, ìpayà lọ́tùn-ún ati lósì ni OLUWA pè ọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 20

Wo Jeremaya 20:3 ni o tọ