Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 20:14-16 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Ègún ni fún ọjọ́ tí a bí mi,kí ọjọ́ tí ìyá mi bí mi má jẹ́ ọjọ́ ayọ̀.

15. Ègún ni fún ẹni tí ó yọ̀ fún baba mi,tí ó sọ fún un pé,“Iyawo rẹ ti bí ọmọkunrin kan fún ọ,tí ó mú inú rẹ̀ dùn.”

16. Kí olúwarẹ̀ dàbí àwọn ìlú tí OLUWA parun láìṣàánú wọn.Kí ó gbọ́ igbe lówùúrọ̀,ati ariwo ìdágìrì lọ́sàn-án gangan.

Ka pipe ipin Jeremaya 20