Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 2:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ìran yìí, ẹ gbọ́ ohun tí èmi, OLUWA ń sọ.Ṣé aṣálẹ̀ ni mo jẹ́ fún Israẹli;tabi mo ti di ilẹ̀ òkùnkùn biribiri?Kí ló dé tí ẹ̀yin eniyan mi fí ń sọ pé,‘A ti di òmìnira, a lè máa káàkiri;a kò ní wá sí ọ̀dọ̀ rẹ mọ́?’

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:31 ni o tọ