Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 2:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn níbo ni àwọn oriṣa yín tí ẹ dá fún ara yín wà?Kí wọn dìde, tí wọ́n bá lè gbà yín ní àkókò ìṣòro yín!Ṣebí bí ìlú yín ti pọ̀ tó, bẹ́ẹ̀ ni àwọn oriṣa yín náà pọ̀ tó, ẹ̀yin ará Juda.

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:28 ni o tọ