Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dàbíi Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ìgbẹ́, tí aṣálẹ̀ ti mọ́ lára,tí ń ṣí imú kiri,nígbà tí ó ń wa akọ tí yóo gùn ún.Ta ló lè dá a dúró?Kí akọ tí ó bá ń wá amá wulẹ̀ ṣe ara rẹ̀ ní wahala,nítorí yóo yọjú nígbà tí àkókò gígùn rẹ̀ bá tó.

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:24 ni o tọ