Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

kí n sì sọ fún wọn pé, OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, “Bí ẹni fọ́ ìkòkò amọ̀ ni n óo ṣe fọ́ àwọn eniyan yìí ati ìlú yìí, kò sì ní ní àtúnṣe mọ́. Ní Tofeti ni wọn yóo máa sin òkú sí nígbà tí wọn kò bá rí ààyè sin òkú sí mọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 19

Wo Jeremaya 19:11 ni o tọ