Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ibi ni eniyan fi í san rere?Sibẹ wọ́n ti wa kòtò sílẹ̀ fún mi.Ranti bí mo ti dúró níwájú rẹ tí mo sọ ọ̀rọ̀ wọn ní rere,kí o baà lè yí ibinu rẹ pada lórí wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 18

Wo Jeremaya 18:20 ni o tọ