Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 17:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ kò bá fetí sí ọ̀rọ̀ mi, tí ẹ kò ya ọjọ́ ìsinmi sí mímọ́, tí ẹ̀ ń ru ẹrù wọ inú Jerusalẹmu lọ́jọ́ ìsinmi, n óo ṣá iná sí ẹnubodè Jerusalẹmu, yóo jó àwọn ààfin rẹ̀, kò sì ní ṣe é pa.’ ”

Ka pipe ipin Jeremaya 17

Wo Jeremaya 17:27 ni o tọ