Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní: ‘Wò ó! N óo fi òpin sí ẹ̀rín ati ìró ayọ̀ ní ibí yìí, n óo sì fi òpin sí ohùn iyawo àṣẹ̀ṣẹ̀gbé ati ti ọkọ iyawo. Yóo ṣẹlẹ̀ bẹ́ẹ̀ níṣojú yín, ní ìgbà ayé yín.’

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:9 ni o tọ