Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sí ẹni tí yóo fún ẹni tí ń ṣọ̀fọ̀ ní oúnjẹ láti tù ú ninu, bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kò sì ní bu omi fún ẹnìkan mu, nítorí ikú baba tabi ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:7 ni o tọ