Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Má wọ ilé tí wọ́n ti ń ṣọ̀fọ̀, má lọ máa kọrin arò, tabi kí o bá wọn kẹ́dùn, nítorí mo ti mú alaafia mi ati ìfẹ́ mi ati àánú mi kúrò lọ́dọ̀ àwọn eniyan wọnyi.

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:5 ni o tọ