Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:19 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ìwọ ni agbára mi, ati ibi ààbò mi,ìwọ ni ibi ìsápamọ́sí mi, ní ìgbà ìpọ́njú.Àwọn orílẹ̀-èdè yóo wá sọ́dọ̀ rẹ,láti gbogbo òpin ayé,wọn yóo máa wí pé:“Irọ́ patapata ni àwọn baba wa jogún,ère lásánlàsàn tí kò ní èrè kankan.

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:19 ni o tọ