Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo gba yín dànù kúrò ní ilẹ̀ yìí; n óo fọn yín dànù bí òkò, sí ilẹ̀ tí ẹ̀yin ati àwọn baba yín kò mọ̀ rí. Níbẹ̀ ni ẹ óo ti máa sin oriṣa, tí ẹ óo máa bọ wọ́n tọ̀sán-tòru, nítorí pé n kò ní ṣàánú yín.”

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:13 ni o tọ