Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti fẹ́ wọn bí ẹni fẹ́ ọkà ní ibi ìpakà,ní ẹnubodè ilẹ̀ náà.Mo ti kó ọ̀fọ̀ bá wọn;mo ti pa àwọn eniyan mi run,nítorí wọn kò yipada kúrò ní ọ̀nà wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 15

Wo Jeremaya 15:7 ni o tọ