Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 15:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbé! Ìyá mi, kí ló dé tí o bí mi, èmi tí mo di oníjà ati alárìíyànjiyàn láàrin gbogbo ìlú! N kò yá ẹnikẹ́ni lówó, bẹ́ẹ̀ n kò yáwó lọ́wọ́ ẹnìkan, sibẹsibẹ gbogbo wọn ni wọ́n ń ṣépè lé mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 15

Wo Jeremaya 15:10 ni o tọ