Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá tún sọ fún mi pé, “Mose ati Samuẹli ìbáà wá dúró níwájú mi, ọkàn mi kò lè yọ́ sí àwọn eniyan wọnyi. Lé wọn kúrò níwájú mi, kí wọ́n máa lọ!

Ka pipe ipin Jeremaya 15

Wo Jeremaya 15:1 ni o tọ