Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ṣé o ti kọ Juda sílẹ̀ patapata ni?Àbí Sioni ti di ohun ìríra lọ́kàn rẹ?Kí ló dé tí o fi lù wá,tóbẹ́ẹ̀ tí ọ̀rọ̀ tiwa kọjá ìwòsàn?À ń retí alaafia, ṣugbọn ire kankan kò dé.À ń retí àkókò ìwòsàn, ṣugbọn ìpayà ni a rí.

Ka pipe ipin Jeremaya 14

Wo Jeremaya 14:19 ni o tọ