Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo gbé àwọn eniyan tí wọn ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún sọ síta ní òkú ní ìgboro Jerusalẹmu, nígbà tí ìyàn ati ogun bá pa wọ́n tán. Kò ní sí ẹni tí yóo sin òkú wọn, ati ti àwọn iyawo wọn, ati ti àwọn ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin. N óo da ibi tí wọ́n ṣe lé wọn lórí.”

Ka pipe ipin Jeremaya 14

Wo Jeremaya 14:16 ni o tọ