Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo máa sọ wọ́n lu ara wọn. Baba ati ọmọ yóo máa kọlu ara wọn. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀. N kò ní ṣàánú wọn, n kò ní dá ẹnikẹ́ni sí, n kò sì ní yọ́nú sí wọn débi pé kí n má fẹ́ pa wọ́n run.”

Ka pipe ipin Jeremaya 13

Wo Jeremaya 13:14 ni o tọ