Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Sọ fún wọn pé, èmi OLUWA Ọlọrun Israẹli ní, ‘Gbogbo ìkòkò ni a óo rọ ọtí waini kún.’ Wọn yóo dá ọ lóhùn pé, ‘Ṣé a kò mọ̀ pé gbogbo ìkòkò ni a óo rọ ọtí waini kún ni?’

Ka pipe ipin Jeremaya 13

Wo Jeremaya 13:12 ni o tọ