Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 12:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó bá yá, bí wọ́n bá fi tọkàntọkàn kọ́ àṣà àwọn eniyan mi, tí wọ́n sì ń fi orúkọ mi búra, tí wọn ń wí pé, ‘Bí OLUWA Ọlọrun ti wà láàyè’, bí àwọn náà ṣe kọ́ àwọn eniyan mi láti máa fi orúkọ Baali búra, n óo fi ìdí wọn múlẹ̀ láàrin àwọn eniyan mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:16 ni o tọ