Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 12:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí OLUWA sọ nípa gbogbo àwọn aládùúgbò burúkú mi nìyí, àwọn tí wọn ń jí bù lára ilẹ̀ tí mo fún Israẹli, àwọn eniyan mi. Ó ní, “N óo kó wọn kúrò lórí ilẹ̀ wọn; n óo sì kó àwọn ọmọ Juda kúrò láàrin wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:14 ni o tọ