Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn onídàájọ́ òdodo ni ọ́, OLUWA àwọn ọmọ ogun, ẹni tí ó ń dán ọkàn ati èrò eniyan wò, jẹ́ kí n rí i bí o óo ṣe máa gbẹ̀san lára wọn; nítorí pé ìwọ ni mo fi ọ̀rọ̀ mi lé lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:20 ni o tọ