Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà kan rí, OLUWA pè ọ́ ní igi olifi eléwé tútù, tí èso rẹ̀ dára; ṣugbọn pẹlu ìró ìjì ńlá, yóo dáná sun ún, gbogbo ẹ̀ka rẹ̀ yóo sì jóná.

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:16 ni o tọ