Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, má ṣe gbadura fún àwọn eniyan wọnyi. Má sọkún nítorí wọn, má sì bẹ̀bẹ̀ fún wọn, nítorí n kò ní gbọ́, nígbà tí wọn bá ké pè mí nígbà ìṣòro wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:14 ni o tọ