Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 11:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA bá èmi Jeremaya sọ̀rọ̀,

2. ó ní, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ majẹmu yìí, kí o sì sọ ọ́ fún àwọn ọmọ Juda, ati àwọn tí ń gbé Jerusalẹmu.

3. Sọ fún wọn pé OLUWA Ọlọrun Israẹli ní, ‘Ẹnikẹ́ni tí kò bá gba ọ̀rọ̀ majẹmu

Ka pipe ipin Jeremaya 11