Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 1:4-7 BIBELI MIMỌ (BM)

4. OLUWA sọ fún mi pé,

5. “Kí n tó dá ọ sinu ìyá rẹ ni mo ti mọ̀ ọ́,kí wọ́n sì tó bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀,mo yàn ọ́ ní wolii fún àwọn orílẹ̀-èdè.”

6. Mo bá dáhùn pé,“Háà! OLUWA Ọlọrun!Wò ó! N kò mọ ọ̀rọ̀ sọ, nítorí pé ọmọde ni mí.”

7. Ṣugbọn OLUWA dá mi lóhùn, ó ní,“Má pe ara rẹ ní ọmọde,nítorí pé gbogbo ẹni tí mo bá rán ọ sí ni o gbọdọ̀ tọ̀ lọ.Gbogbo ohun tí mo bá pa láṣẹ fún ọ ni o gbọdọ̀ sọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 1