Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó, mo ti sọ ọ́ di ìlú tí a mọ odi yíká lónìí, o di òpó irin ati ògiri tí a fi bàbà mọ fún gbogbo ilẹ̀ yìí, ati fún àwọn ọba ilẹ̀ Juda, àwọn ìjòyè, ati àwọn alufaa rẹ̀, ati àwọn eniyan ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jeremaya 1

Wo Jeremaya 1:18 ni o tọ