Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tún bi mí lẹẹkeji, ó ní, “Kí ni o rí?”Mo bá dáhùn pé, “Mo rí ìkòkò kan tí ó ń hó lórí iná, ó tẹ̀ láti ìhà àríwá sí ìhà gúsù.”

Ka pipe ipin Jeremaya 1

Wo Jeremaya 1:13 ni o tọ