Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Dájúdájú n óo gbẹ̀san lára ẹnikẹ́ni tí ó bá paniyan, kì báà jẹ́ ẹranko ni ó paniyan tabi eniyan ni ó pa ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, pípa ni a óo pa olúwarẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 9

Wo Jẹnẹsisi 9:5 ni o tọ