Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Omi náà sì ń fà sí i títí di oṣù kẹwaa. Ní ọjọ́ kinni oṣù náà ni ṣóńṣó orí àwọn òkè ńlá hàn síta.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 8

Wo Jẹnẹsisi 8:5 ni o tọ