Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun ranti Noa, ati gbogbo ẹranko, ati ẹran ọ̀sìn tí ó wà pẹlu rẹ̀ ninu ọkọ̀. Nítorí náà, Ọlọrun mú kí afẹ́fẹ́ kan fẹ́ sórí ilẹ̀, omi náà sì bẹ̀rẹ̀ sí fà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 8

Wo Jẹnẹsisi 8:1 ni o tọ