Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ẹ̀dá alààyè tí wọ́n wà lórí ilẹ̀ ayé ni wọ́n kú patapata, ati ẹyẹ, ati ẹran ọ̀sìn, ati ẹranko, ati àwọn ohun tí wọn ń fàyà fà ati eniyan.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7

Wo Jẹnẹsisi 7:21 ni o tọ