Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹnẹsisi 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ohun ẹlẹ́mìí, akọ kan, abo kan, ní oríṣìí kọ̀ọ̀kan wọlé gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti pàṣẹ fún Noa. OLUWA bá ti ìlẹ̀kùn ọkọ̀ náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 7

Wo Jẹnẹsisi 7:16 ni o tọ